Quran with Yoruba translation - Surah Hud ayat 26 - هُود - Page - Juz 12
﴿أَن لَّا تَعۡبُدُوٓاْ إِلَّا ٱللَّهَۖ إِنِّيٓ أَخَافُ عَلَيۡكُمۡ عَذَابَ يَوۡمٍ أَلِيمٖ ﴾
[هُود: 26]
﴿أن لا تعبدوا إلا الله إني أخاف عليكم عذاب يوم أليم﴾ [هُود: 26]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Mò ń kìlọ̀) pé kí ẹ má ṣe jọ́sìn fún ẹnì kan àfi Allāhu. Dájúdájú èmi ń páyà ìyà ọjọ́ ẹlẹ́ta-eléro fun yín |