×

Eyin ijo mi, e toro aforijin lodo Oluwa Eledaa yin, leyin naa, 11:52 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Hud ⮕ (11:52) ayat 52 in Yoruba

11:52 Surah Hud ayat 52 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Hud ayat 52 - هُود - Page - Juz 12

﴿وَيَٰقَوۡمِ ٱسۡتَغۡفِرُواْ رَبَّكُمۡ ثُمَّ تُوبُوٓاْ إِلَيۡهِ يُرۡسِلِ ٱلسَّمَآءَ عَلَيۡكُم مِّدۡرَارٗا وَيَزِدۡكُمۡ قُوَّةً إِلَىٰ قُوَّتِكُمۡ وَلَا تَتَوَلَّوۡاْ مُجۡرِمِينَ ﴾
[هُود: 52]

Eyin ijo mi, e toro aforijin lodo Oluwa Eledaa yin, leyin naa, ki e ronu piwada sodo Re nitori ki O le rojo fun yin ni pupo lati sanmo ati nitori ki O le se alekun agbara kun agbara yin. E ma se peyin da lati di elese (sinu aigbagbo)

❮ Previous Next ❯

ترجمة: وياقوم استغفروا ربكم ثم توبوا إليه يرسل السماء عليكم مدرارا ويزدكم قوة, باللغة اليوربا

﴿وياقوم استغفروا ربكم ثم توبوا إليه يرسل السماء عليكم مدرارا ويزدكم قوة﴾ [هُود: 52]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Ẹ̀yin ìjọ mi, ẹ tọrọ àforíjìn lọ́dọ̀ Olùwa Ẹlẹ́dàá yín, lẹ́yìn náà, kí ẹ ronú pìwàdà sọ́dọ̀ Rẹ̀ nítorí kí Ó lè rọ̀jò fun yín ní púpọ̀ láti sánmọ̀ àti nítorí kí Ó lè ṣe àlékún agbára kún agbára yín. Ẹ má ṣe pẹ̀yìn dà láti di ẹlẹ́ṣẹ̀ (sínú àìgbàgbọ́)
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek