Quran with Yoruba translation - Surah Hud ayat 80 - هُود - Page - Juz 12
﴿قَالَ لَوۡ أَنَّ لِي بِكُمۡ قُوَّةً أَوۡ ءَاوِيٓ إِلَىٰ رُكۡنٖ شَدِيدٖ ﴾
[هُود: 80]
﴿قال لو أن لي بكم قوة أو آوي إلى ركن شديد﴾ [هُود: 80]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó sọ pé: "Tí ó bá jẹ́ pé dájúdájú agbára kan wà fún mi lórí yín ni, tàbí (pé) mo lè darapọ̀ mọ́ ẹbí kan t’ó lágbára ni, (èmi ìbá di yín lọ́wọ́ níbi aburú yín) |