Quran with Yoruba translation - Surah Yusuf ayat 101 - يُوسُف - Page - Juz 13
﴿۞ رَبِّ قَدۡ ءَاتَيۡتَنِي مِنَ ٱلۡمُلۡكِ وَعَلَّمۡتَنِي مِن تَأۡوِيلِ ٱلۡأَحَادِيثِۚ فَاطِرَ ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضِ أَنتَ وَلِيِّۦ فِي ٱلدُّنۡيَا وَٱلۡأٓخِرَةِۖ تَوَفَّنِي مُسۡلِمٗا وَأَلۡحِقۡنِي بِٱلصَّٰلِحِينَ ﴾
[يُوسُف: 101]
﴿رب قد آتيتني من الملك وعلمتني من تأويل الأحاديث فاطر السموات والأرض﴾ [يُوسُف: 101]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Olúwa mi, dájúdájú O ti fún mi ni ìjọba. O tún fún mi ni ìmọ̀ ìtúmọ̀ àlá. Olùpilẹ̀dá àwọn sánmọ̀ àti ilẹ̀, Ìwọ ni Olùrànlọ́wọ́ mi ní ayé àti ní ọ̀run, pa mi sípò mùsùlùmí. Kí O sì fi mí pẹ̀lú àwọn ẹni rere.” |