Quran with Yoruba translation - Surah Yusuf ayat 12 - يُوسُف - Page - Juz 12
﴿أَرۡسِلۡهُ مَعَنَا غَدٗا يَرۡتَعۡ وَيَلۡعَبۡ وَإِنَّا لَهُۥ لَحَٰفِظُونَ ﴾
[يُوسُف: 12]
﴿أرسله معنا غدا يرتع ويلعب وإنا له لحافظون﴾ [يُوسُف: 12]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Jẹ́ kí ó bá wa lọ ní ọ̀la nítorí kí ó lè dára yá, kí ó sì lè ṣeré. Àti pé dájúdájú àwa ni olùṣọ́ fún un.” |