Quran with Yoruba translation - Surah Yusuf ayat 11 - يُوسُف - Page - Juz 12
﴿قَالُواْ يَٰٓأَبَانَا مَا لَكَ لَا تَأۡمَ۬نَّا عَلَىٰ يُوسُفَ وَإِنَّا لَهُۥ لَنَٰصِحُونَ ﴾
[يُوسُف: 11]
﴿قالوا ياأبانا ما لك لا تأمنا على يوسف وإنا له لناصحون﴾ [يُوسُف: 11]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n sọ pé: “Bàbá wa, kí ni kò mú ọ fi ọkàn tán wa lórí Yūsuf. Dájúdájú àwa sì máa jẹ́ olùtọ́jú rẹ̀ |