Quran with Yoruba translation - Surah Yusuf ayat 57 - يُوسُف - Page - Juz 13
﴿وَلَأَجۡرُ ٱلۡأٓخِرَةِ خَيۡرٞ لِّلَّذِينَ ءَامَنُواْ وَكَانُواْ يَتَّقُونَ ﴾
[يُوسُف: 57]
﴿ولأجر الآخرة خير للذين آمنوا وكانوا يتقون﴾ [يُوسُف: 57]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú ẹ̀san ti ọ̀run lóore jùlọ fún àwọn t’ó gbàgbọ́ ní òdodo, tí wọ́n sì ń bẹ̀rù (Allāhu) |