Quran with Yoruba translation - Surah Yusuf ayat 9 - يُوسُف - Page - Juz 12
﴿ٱقۡتُلُواْ يُوسُفَ أَوِ ٱطۡرَحُوهُ أَرۡضٗا يَخۡلُ لَكُمۡ وَجۡهُ أَبِيكُمۡ وَتَكُونُواْ مِنۢ بَعۡدِهِۦ قَوۡمٗا صَٰلِحِينَ ﴾
[يُوسُف: 9]
﴿اقتلوا يوسف أو اطرحوه أرضا يخل لكم وجه أبيكم وتكونوا من بعده﴾ [يُوسُف: 9]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ pa Yūsuf tàbí kí ẹ lọ gbé e jùnù sí ilẹ̀ (mìíràn) nítorí kí bàbá yín lè rójú gbọ́ tiyín. Ẹ sì máa di ènìyàn rere lẹ́yìn rẹ̀ |