×

So pe: “Ta ni Oluwa awon sanmo ati ile?” So pe: “Allahu 13:16 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Ar-Ra‘d ⮕ (13:16) ayat 16 in Yoruba

13:16 Surah Ar-Ra‘d ayat 16 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Ar-Ra‘d ayat 16 - الرَّعد - Page - Juz 13

﴿قُلۡ مَن رَّبُّ ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضِ قُلِ ٱللَّهُۚ قُلۡ أَفَٱتَّخَذۡتُم مِّن دُونِهِۦٓ أَوۡلِيَآءَ لَا يَمۡلِكُونَ لِأَنفُسِهِمۡ نَفۡعٗا وَلَا ضَرّٗاۚ قُلۡ هَلۡ يَسۡتَوِي ٱلۡأَعۡمَىٰ وَٱلۡبَصِيرُ أَمۡ هَلۡ تَسۡتَوِي ٱلظُّلُمَٰتُ وَٱلنُّورُۗ أَمۡ جَعَلُواْ لِلَّهِ شُرَكَآءَ خَلَقُواْ كَخَلۡقِهِۦ فَتَشَٰبَهَ ٱلۡخَلۡقُ عَلَيۡهِمۡۚ قُلِ ٱللَّهُ خَٰلِقُ كُلِّ شَيۡءٖ وَهُوَ ٱلۡوَٰحِدُ ٱلۡقَهَّٰرُ ﴾
[الرَّعد: 16]

So pe: “Ta ni Oluwa awon sanmo ati ile?” So pe: “Allahu ni.” So pe: “Se leyin Re ni e tun mu awon alafeyinti kan, ti won ko ni ikapa oore ati inira fun emi ara won?” So pe: “Se afoju ati oluriran dogba bi? Tabi awon okunkun ati imole dogba? Tabi won yoo fun Allahu ni awon akegbe kan ti awon naa da eda bii ti eda Re, (to bee ge) ti eda fi jora won loju won?” So pe: “Allahu ni Eledaa gbogbo nnkan. Oun si ni Okan soso, Olubori

❮ Previous Next ❯

ترجمة: قل من رب السموات والأرض قل الله قل أفاتخذتم من دونه أولياء, باللغة اليوربا

﴿قل من رب السموات والأرض قل الله قل أفاتخذتم من دونه أولياء﴾ [الرَّعد: 16]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Sọ pé: “Ta ni Olúwa àwọn sánmọ̀ àti ilẹ̀?” Sọ pé: “Allāhu ni.” Sọ pé: “Ṣé lẹ́yìn Rẹ̀ ni ẹ tún mú àwọn aláfẹ̀yìntì kan, tí wọn kò ní ìkápá oore àti ìnira fún ẹ̀mí ara wọn?” Sọ pé: “Ṣé afọ́jú àti olùríran dọ́gba bí? Tàbí àwọn òkùnkùn àti ìmọ́lẹ̀ dọ́gba? Tàbí wọ́n yóò fún Allāhu ní àwọn akẹgbẹ́ kan tí àwọn náà dá ẹ̀dá bíi ti ẹ̀dá Rẹ̀, (tó bẹ́ẹ̀ gẹ́) tí ẹ̀dá fi jọra wọn lójú wọn?” Sọ pé: “Allāhu ni Ẹlẹ́dàá gbogbo n̄ǹkan. Òun sì ni Ọ̀kan ṣoṣo, Olùborí
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek