×

O n so omi kale lati sanmo. Awon oju-odo si n san 13:17 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Ar-Ra‘d ⮕ (13:17) ayat 17 in Yoruba

13:17 Surah Ar-Ra‘d ayat 17 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Ar-Ra‘d ayat 17 - الرَّعد - Page - Juz 13

﴿أَنزَلَ مِنَ ٱلسَّمَآءِ مَآءٗ فَسَالَتۡ أَوۡدِيَةُۢ بِقَدَرِهَا فَٱحۡتَمَلَ ٱلسَّيۡلُ زَبَدٗا رَّابِيٗاۖ وَمِمَّا يُوقِدُونَ عَلَيۡهِ فِي ٱلنَّارِ ٱبۡتِغَآءَ حِلۡيَةٍ أَوۡ مَتَٰعٖ زَبَدٞ مِّثۡلُهُۥۚ كَذَٰلِكَ يَضۡرِبُ ٱللَّهُ ٱلۡحَقَّ وَٱلۡبَٰطِلَۚ فَأَمَّا ٱلزَّبَدُ فَيَذۡهَبُ جُفَآءٗۖ وَأَمَّا مَا يَنفَعُ ٱلنَّاسَ فَيَمۡكُثُ فِي ٱلۡأَرۡضِۚ كَذَٰلِكَ يَضۡرِبُ ٱللَّهُ ٱلۡأَمۡثَالَ ﴾
[الرَّعد: 17]

O n so omi kale lati sanmo. Awon oju-odo si n san pelu odiwon re. Agbara si n gbe ifofo ori-omi lo. Bakan naa, ninu nnkan ti won n yo ninu ina lati fi se nnkan-oso tabi nnkan-elo, ohun naa ni ifofo bi iru re. Bayen ni Allahu se n mu apejuwe ododo ati iro wa. Ni ti ifofo, o maa ba panti lo. Ni ti eyi ti o si maa se eniyan ni anfaani, o maa duro si ori ile. Bayen ni Allahu se n mu apejuwe wa

❮ Previous Next ❯

ترجمة: أنـزل من السماء ماء فسالت أودية بقدرها فاحتمل السيل زبدا رابيا ومما, باللغة اليوربا

﴿أنـزل من السماء ماء فسالت أودية بقدرها فاحتمل السيل زبدا رابيا ومما﴾ [الرَّعد: 17]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Ó ń sọ omi kalẹ̀ láti sánmọ̀. Àwọn ojú-odò sì ń ṣàn pẹ̀lú òdiwọ̀n rẹ̀. Àgbàrá sì ń gbé ìfòfó orí-omi lọ. Bákan náà, nínú n̄ǹkan tí wọ́n ń yọ́ nínú iná láti fi ṣe n̄ǹkan-ọ̀ṣọ́ tàbí n̄ǹkan-èlò, òhun náà ní ìfòfó bí irú rẹ̀. Báyẹn ni Allāhu ṣe ń mú àpèjúwe òdodo àti irọ́ wá. Ní ti ìfòfó, ó máa bá pàǹtí lọ. Ní ti èyí tí ó sì máa ṣe ènìyàn ní àǹfààní, ó máa dúró sí orí ilẹ̀. Báyẹn ni Allāhu ṣe ń mú àpèjúwe wá
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek