Quran with Yoruba translation - Surah Ibrahim ayat 29 - إبراهِيم - Page - Juz 13
﴿جَهَنَّمَ يَصۡلَوۡنَهَاۖ وَبِئۡسَ ٱلۡقَرَارُ ﴾
[إبراهِيم: 29]
﴿جهنم يصلونها وبئس القرار﴾ [إبراهِيم: 29]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Iná Jahanamọ ni wọn yóò gúnlẹ̀ sí; ibùgbé náà sì burú |