Quran with Yoruba translation - Surah Ibrahim ayat 51 - إبراهِيم - Page - Juz 13
﴿لِيَجۡزِيَ ٱللَّهُ كُلَّ نَفۡسٖ مَّا كَسَبَتۡۚ إِنَّ ٱللَّهَ سَرِيعُ ٱلۡحِسَابِ ﴾
[إبراهِيم: 51]
﴿ليجزي الله كل نفس ما كسبت إن الله سريع الحساب﴾ [إبراهِيم: 51]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni nítorí kí Allāhu lè san ẹ̀san ohun tí ẹ̀mí kọ̀ọ̀kan ṣe níṣẹ́. Dájúdájú Allāhu ni Olùyára níbi ìṣírò-iṣẹ́ |