×

Eyi ni ise-jije fun awon eniyan nitori ki won le fi se 14:52 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Ibrahim ⮕ (14:52) ayat 52 in Yoruba

14:52 Surah Ibrahim ayat 52 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Ibrahim ayat 52 - إبراهِيم - Page - Juz 13

﴿هَٰذَا بَلَٰغٞ لِّلنَّاسِ وَلِيُنذَرُواْ بِهِۦ وَلِيَعۡلَمُوٓاْ أَنَّمَا هُوَ إِلَٰهٞ وَٰحِدٞ وَلِيَذَّكَّرَ أُوْلُواْ ٱلۡأَلۡبَٰبِ ﴾
[إبراهِيم: 52]

Eyi ni ise-jije fun awon eniyan nitori ki won le fi se ikilo, ki won si le mo pe (Allahu) Oun nikan ni Olohun ti ijosin to si, Okan soso, ati nitori ki awon onilaakaye le lo iranti

❮ Previous Next ❯

ترجمة: هذا بلاغ للناس ولينذروا به وليعلموا أنما هو إله واحد وليذكر أولو, باللغة اليوربا

﴿هذا بلاغ للناس ولينذروا به وليعلموا أنما هو إله واحد وليذكر أولو﴾ [إبراهِيم: 52]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Èyí ni iṣẹ́-jíjẹ́ fún àwọn ènìyàn nítorí kí wọ́n lè fi ṣe ìkìlọ̀, kí wọ́n sì lè mọ̀ pé (Allāhu) Òun nìkan ni Ọlọ́hun tí ìjọ́sìn tọ́ sí, Ọ̀kan ṣoṣo, àti nítorí kí àwọn onílàákàyè lè lo ìrántí
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek