Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 74 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿فَجَعَلۡنَا عَٰلِيَهَا سَافِلَهَا وَأَمۡطَرۡنَا عَلَيۡهِمۡ حِجَارَةٗ مِّن سِجِّيلٍ ﴾
[الحِجر: 74]
﴿فجعلنا عاليها سافلها وأمطرنا عليهم حجارة من سجيل﴾ [الحِجر: 74]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A sì sọ òkè ìlú wọn di ìsàlẹ̀ rẹ̀ (ìlú wọ́n dojú bolẹ̀). A tún rọ òjò òkúta amọ̀ (sísun) lé wọn lórí |