Quran with Yoruba translation - Surah An-Nahl ayat 55 - النَّحل - Page - Juz 14
﴿لِيَكۡفُرُواْ بِمَآ ءَاتَيۡنَٰهُمۡۚ فَتَمَتَّعُواْ فَسَوۡفَ تَعۡلَمُونَ ﴾
[النَّحل: 55]
﴿ليكفروا بما آتيناهم فتمتعوا فسوف تعلمون﴾ [النَّحل: 55]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni nítorí kí wọ́n lè ṣàì moore sí n̄ǹkan tí A fún wọn. Nítorí náà, ẹ máa gbádùn ǹsó. Láìpẹ́ ẹ máa mọ̀ |