Quran with Yoruba translation - Surah An-Nahl ayat 54 - النَّحل - Page - Juz 14
﴿ثُمَّ إِذَا كَشَفَ ٱلضُّرَّ عَنكُمۡ إِذَا فَرِيقٞ مِّنكُم بِرَبِّهِمۡ يُشۡرِكُونَ ﴾
[النَّحل: 54]
﴿ثم إذا كشف الضر عنكم إذا فريق منكم بربهم يشركون﴾ [النَّحل: 54]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Lẹ́yìn náà, nígbà tí Ó bá sì mú ìnira náà kúrò fun yín tán, nígbà náà ni apá kan nínú yín yó sì máa ṣẹbọ sí Olúwa wọn |