Quran with Yoruba translation - Surah An-Nahl ayat 87 - النَّحل - Page - Juz 14
﴿وَأَلۡقَوۡاْ إِلَى ٱللَّهِ يَوۡمَئِذٍ ٱلسَّلَمَۖ وَضَلَّ عَنۡهُم مَّا كَانُواْ يَفۡتَرُونَ ﴾
[النَّحل: 87]
﴿وألقوا إلى الله يومئذ السلم وضل عنهم ما كانوا يفترون﴾ [النَّحل: 87]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n sì máa jura wọn sílẹ̀ fún Allāhu ní ọjọ́ yẹn. Ohun tí wọ́n ń dá ní àdápa irọ́ yó sì di òfò mọ́ wọn lọ́wọ́ |