×

Fi ohun re ko eni ti agbara re ba ka ninu won 17:64 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Isra’ ⮕ (17:64) ayat 64 in Yoruba

17:64 Surah Al-Isra’ ayat 64 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Isra’ ayat 64 - الإسرَاء - Page - Juz 15

﴿وَٱسۡتَفۡزِزۡ مَنِ ٱسۡتَطَعۡتَ مِنۡهُم بِصَوۡتِكَ وَأَجۡلِبۡ عَلَيۡهِم بِخَيۡلِكَ وَرَجِلِكَ وَشَارِكۡهُمۡ فِي ٱلۡأَمۡوَٰلِ وَٱلۡأَوۡلَٰدِ وَعِدۡهُمۡۚ وَمَا يَعِدُهُمُ ٱلشَّيۡطَٰنُ إِلَّا غُرُورًا ﴾
[الإسرَاء: 64]

Fi ohun re ko eni ti agbara re ba ka ninu won laya je. Fi awon omo ogun elesin re ati omo ogun elese re pe won (sinu isina). Kopa pelu won ninu awon dukia ati awon omo. Ki o si se ileri fun won." Esu ko si nii se ileri fun won bi ko se etan

❮ Previous Next ❯

ترجمة: واستفزز من استطعت منهم بصوتك وأجلب عليهم بخيلك ورجلك وشاركهم في الأموال, باللغة اليوربا

﴿واستفزز من استطعت منهم بصوتك وأجلب عليهم بخيلك ورجلك وشاركهم في الأموال﴾ [الإسرَاء: 64]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Fi ohùn rẹ kó ẹni tí agbára rẹ bá ká nínú wọn láyà jẹ. Fi àwọn ọmọ ogun ẹlẹ́sin rẹ àti ọmọ ogun ẹlẹ́sẹ̀ rẹ pè wọ́n (sínú ìṣìnà). Kópa pẹ̀lú wọn nínú àwọn dúkìá àti àwọn ọmọ. Kí o sì ṣe ìlérí fún wọn." Èṣù kò sì níí ṣe ìlérí fún wọn bí kò ṣe ẹ̀tàn
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek