×

Gbe irun kiki duro ni (igba ti) oorun ba yetari titi di 17:78 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Isra’ ⮕ (17:78) ayat 78 in Yoruba

17:78 Surah Al-Isra’ ayat 78 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Isra’ ayat 78 - الإسرَاء - Page - Juz 15

﴿أَقِمِ ٱلصَّلَوٰةَ لِدُلُوكِ ٱلشَّمۡسِ إِلَىٰ غَسَقِ ٱلَّيۡلِ وَقُرۡءَانَ ٱلۡفَجۡرِۖ إِنَّ قُرۡءَانَ ٱلۡفَجۡرِ كَانَ مَشۡهُودٗا ﴾
[الإسرَاء: 78]

Gbe irun kiki duro ni (igba ti) oorun ba yetari titi di igba ti ale yoo fi le. Ati pe irun Subh, dajudaju irun Subh je ohun ti (awon molaika ale ati osan) yoo jerii si

❮ Previous Next ❯

ترجمة: أقم الصلاة لدلوك الشمس إلى غسق الليل وقرآن الفجر إن قرآن الفجر, باللغة اليوربا

﴿أقم الصلاة لدلوك الشمس إلى غسق الليل وقرآن الفجر إن قرآن الفجر﴾ [الإسرَاء: 78]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Gbé ìrun kíkí dúró ní (ìgbà tí) òòrùn bá yẹ̀tàrí títí di ìgbà tí alẹ́ yóò fi lẹ́. Àti pé ìrun Subh, dájúdájú ìrun Subh jẹ́ ohun tí (àwọn mọlāika alẹ́ àti ọ̀sán) yóò jẹ́rìí sí
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek