×

O le je pe Oluwa yin maa saanu yin. Ti e ba 17:8 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Isra’ ⮕ (17:8) ayat 8 in Yoruba

17:8 Surah Al-Isra’ ayat 8 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Isra’ ayat 8 - الإسرَاء - Page - Juz 15

﴿عَسَىٰ رَبُّكُمۡ أَن يَرۡحَمَكُمۡۚ وَإِنۡ عُدتُّمۡ عُدۡنَاۚ وَجَعَلۡنَا جَهَنَّمَ لِلۡكَٰفِرِينَ حَصِيرًا ﴾
[الإسرَاء: 8]

O le je pe Oluwa yin maa saanu yin. Ti e ba si pada (sibi ese), A maa pada (sibi esan). A si se ina Jahanamo ni ewon fun awon alaigbagbo

❮ Previous Next ❯

ترجمة: عسى ربكم أن يرحمكم وإن عدتم عدنا وجعلنا جهنم للكافرين حصيرا, باللغة اليوربا

﴿عسى ربكم أن يرحمكم وإن عدتم عدنا وجعلنا جهنم للكافرين حصيرا﴾ [الإسرَاء: 8]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Ó lè jẹ́ pé Olúwa yín máa ṣàánú yín. Tí ẹ bá sì padà (síbi ẹ̀ṣẹ̀), A máa padà (síbi ẹ̀san). A sì ṣe iná Jahanamọ ní ẹ̀wọ̀n fún àwọn aláìgbàgbọ́
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek