Quran with Yoruba translation - Surah Al-Kahf ayat 27 - الكَهف - Page - Juz 15
﴿وَٱتۡلُ مَآ أُوحِيَ إِلَيۡكَ مِن كِتَابِ رَبِّكَۖ لَا مُبَدِّلَ لِكَلِمَٰتِهِۦ وَلَن تَجِدَ مِن دُونِهِۦ مُلۡتَحَدٗا ﴾
[الكَهف: 27]
﴿واتل ما أوحي إليك من كتاب ربك لا مبدل لكلماته ولن تجد﴾ [الكَهف: 27]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ké ohun tí A fi ránṣẹ́ sí ọ nínú Tírà Olúwa rẹ. Kò sí ẹni tí ó lè yí àwọn ọ̀rọ̀ Rẹ̀ padà. Ìwọ kò sì lè rí ibùsásí kan yàtọ̀ sí ọ̀dọ̀ Rẹ̀ |