×

Emi ko si lero pe Akoko naa maa sele. Ati pe ti 18:36 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Kahf ⮕ (18:36) ayat 36 in Yoruba

18:36 Surah Al-Kahf ayat 36 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Kahf ayat 36 - الكَهف - Page - Juz 15

﴿وَمَآ أَظُنُّ ٱلسَّاعَةَ قَآئِمَةٗ وَلَئِن رُّدِدتُّ إِلَىٰ رَبِّي لَأَجِدَنَّ خَيۡرٗا مِّنۡهَا مُنقَلَبٗا ﴾
[الكَهف: 36]

Emi ko si lero pe Akoko naa maa sele. Ati pe ti won ba da mi pada si odo Oluwa mi, dajudaju mo tun maa ri ibudesi t’o dara ju eyi lo.”

❮ Previous Next ❯

ترجمة: وما أظن الساعة قائمة ولئن رددت إلى ربي لأجدن خيرا منها منقلبا, باللغة اليوربا

﴿وما أظن الساعة قائمة ولئن رددت إلى ربي لأجدن خيرا منها منقلبا﴾ [الكَهف: 36]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Èmi kò sì lérò pé Àkókò náà máa ṣẹlẹ̀. Àti pé tí wọ́n bá dá mi padà sí ọ̀dọ̀ Olúwa mi, dájúdájú mo tún máa rí ibùdésí t’ó dára ju èyí lọ.”
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek