Quran with Yoruba translation - Surah Al-Kahf ayat 38 - الكَهف - Page - Juz 15
﴿لَّٰكِنَّا۠ هُوَ ٱللَّهُ رَبِّي وَلَآ أُشۡرِكُ بِرَبِّيٓ أَحَدٗا ﴾
[الكَهف: 38]
﴿لكنا هو الله ربي ولا أشرك بربي أحدا﴾ [الكَهف: 38]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ṣùgbọ́n ní tèmi, Olúwa mi, Òun ni Allāhu. Èmi kò sì níí sọ ẹnì kan di akẹgbẹ́ fún Olúwa mi |