Quran with Yoruba translation - Surah Al-Kahf ayat 75 - الكَهف - Page - Juz 16
﴿۞ قَالَ أَلَمۡ أَقُل لَّكَ إِنَّكَ لَن تَسۡتَطِيعَ مَعِيَ صَبۡرٗا ﴾
[الكَهف: 75]
﴿قال ألم أقل لك إنك لن تستطيع معي صبرا﴾ [الكَهف: 75]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Kidr) sọ pé: “Ǹjẹ́ mi ò sọ fún ọ pé dájúdájú o ò níí lè ṣe sùúrú pẹ̀lú mi.” |