Quran with Yoruba translation - Surah Al-Kahf ayat 84 - الكَهف - Page - Juz 16
﴿إِنَّا مَكَّنَّا لَهُۥ فِي ٱلۡأَرۡضِ وَءَاتَيۡنَٰهُ مِن كُلِّ شَيۡءٖ سَبَبٗا ﴾
[الكَهف: 84]
﴿إنا مكنا له في الأرض وآتيناه من كل شيء سببا﴾ [الكَهف: 84]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú Àwa fún un ní ipò lórí ilẹ̀. A sì fún un ní ọ̀nà t’ó lè gbà ṣe gbogbo n̄ǹkan (tí ó bá fẹ́ ṣe) |