Quran with Yoruba translation - Surah Al-Kahf ayat 87 - الكَهف - Page - Juz 16
﴿قَالَ أَمَّا مَن ظَلَمَ فَسَوۡفَ نُعَذِّبُهُۥ ثُمَّ يُرَدُّ إِلَىٰ رَبِّهِۦ فَيُعَذِّبُهُۥ عَذَابٗا نُّكۡرٗا ﴾
[الكَهف: 87]
﴿قال أما من ظلم فسوف نعذبه ثم يرد إلى ربه فيعذبه عذابا﴾ [الكَهف: 87]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Allāhu) sọ pé: “Ní ti ẹni tí ó bá ṣàbòsí, láìpẹ́ A máa jẹ ẹ́ níyà. Lẹ́yìn náà, wọn máa dá a padà sí ọ̀dọ̀ Olúwa rẹ̀. Ó sì máa jẹ ẹ́ níyà t’ó burú |