Quran with Yoruba translation - Surah Al-Kahf ayat 97 - الكَهف - Page - Juz 16
﴿فَمَا ٱسۡطَٰعُوٓاْ أَن يَظۡهَرُوهُ وَمَا ٱسۡتَطَٰعُواْ لَهُۥ نَقۡبٗا ﴾ 
[الكَهف: 97]
﴿فما اسطاعوا أن يظهروه وما استطاعوا له نقبا﴾ [الكَهف: 97]
| Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, wọn kò lè gùn ún, wọn kò sì lè dá a lu  |