Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 6 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿يَرِثُنِي وَيَرِثُ مِنۡ ءَالِ يَعۡقُوبَۖ وَٱجۡعَلۡهُ رَبِّ رَضِيّٗا ﴾
[مَريَم: 6]
﴿يرثني ويرث من آل يعقوب واجعله رب رضيا﴾ [مَريَم: 6]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (tí) ó máa jogún mi, tí ó sì máa jogún àwọn ẹbí (Ànábì) Ya‘ƙūb. Kí O sì ṣe é ní ẹni tí O yọ́nú sí, Olúwa mi |