Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 69 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿ثُمَّ لَنَنزِعَنَّ مِن كُلِّ شِيعَةٍ أَيُّهُمۡ أَشَدُّ عَلَى ٱلرَّحۡمَٰنِ عِتِيّٗا ﴾
[مَريَم: 69]
﴿ثم لننـزعن من كل شيعة أيهم أشد على الرحمن عتيا﴾ [مَريَم: 69]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Lẹ́yìn náà, dájúdájú A máa mú jáde nínú ìjọ kọ̀ọ̀kan èyíkéyìí nínú wọn tí ó le jùlọ ní ẹ̀ṣẹ̀ dídá sí Àjọkẹ́-ayé |