Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 70 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿ثُمَّ لَنَحۡنُ أَعۡلَمُ بِٱلَّذِينَ هُمۡ أَوۡلَىٰ بِهَا صِلِيّٗا ﴾
[مَريَم: 70]
﴿ثم لنحن أعلم بالذين هم أولى بها صليا﴾ [مَريَم: 70]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Lẹ́yìn náà, dájúdájú Àwa nímọ̀ jùlọ nípa àwọn t’ó lẹ́tọ̀ọ́ sí wíwọ inú Iná |