Quran with Yoruba translation - Surah Al-Baqarah ayat 117 - البَقَرَة - Page - Juz 1
﴿بَدِيعُ ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضِۖ وَإِذَا قَضَىٰٓ أَمۡرٗا فَإِنَّمَا يَقُولُ لَهُۥ كُن فَيَكُونُ ﴾
[البَقَرَة: 117]
﴿بديع السموات والأرض وإذا قضى أمرا فإنما يقول له كن فيكون﴾ [البَقَرَة: 117]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Olùpilẹ̀dá àwọn sánmọ̀ àti ilẹ̀ ni (Allāhu). Nígbà tí Ó bá sì pèbùbù kiní kan, Ó kàn máa sọ fún un pé: “Jẹ́ bẹ́ẹ̀.” Ó sì máa jẹ́ bẹ́ẹ̀ |