Quran with Yoruba translation - Surah Al-Baqarah ayat 162 - البَقَرَة - Page - Juz 2
﴿خَٰلِدِينَ فِيهَا لَا يُخَفَّفُ عَنۡهُمُ ٱلۡعَذَابُ وَلَا هُمۡ يُنظَرُونَ ﴾
[البَقَرَة: 162]
﴿خالدين فيها لا يخفف عنهم العذاب ولا هم ينظرون﴾ [البَقَرَة: 162]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Olùṣegbére ni wọ́n nínú rẹ̀. Nítorí náà, A ò níí gbé ìyà fúyẹ́ fún wọn. A ò sì níí fún wọn ní ìsinmi (nínú Iná) |