Quran with Yoruba translation - Surah Al-Baqarah ayat 238 - البَقَرَة - Page - Juz 2
﴿حَٰفِظُواْ عَلَى ٱلصَّلَوَٰتِ وَٱلصَّلَوٰةِ ٱلۡوُسۡطَىٰ وَقُومُواْ لِلَّهِ قَٰنِتِينَ ﴾
[البَقَرَة: 238]
﴿حافظوا على الصلوات والصلاة الوسطى وقوموا لله قانتين﴾ [البَقَرَة: 238]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ ṣọ́ àwọn ìrun (wákàtí márààrún) àti (ní pàápàá jùlọ) ìrun ààrin. Kí ẹ sì dúró (kírun gẹ́gẹ́ bí) olùtẹríba fún Allāhu, láì níí sọ̀rọ̀ (mìíràn lórí ìrun) |