Quran with Yoruba translation - Surah Al-Baqarah ayat 242 - البَقَرَة - Page - Juz 2
﴿كَذَٰلِكَ يُبَيِّنُ ٱللَّهُ لَكُمۡ ءَايَٰتِهِۦ لَعَلَّكُمۡ تَعۡقِلُونَ ﴾
[البَقَرَة: 242]
﴿كذلك يبين الله لكم آياته لعلكم تعقلون﴾ [البَقَرَة: 242]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Báyẹn ni Allāhu ṣe ń ṣàlàyé àwọn āyah Rẹ̀ fun yín, nítorí kí ẹ lè ṣe làákàyè |