Quran with Yoruba translation - Surah Al-Baqarah ayat 53 - البَقَرَة - Page - Juz 1
﴿وَإِذۡ ءَاتَيۡنَا مُوسَى ٱلۡكِتَٰبَ وَٱلۡفُرۡقَانَ لَعَلَّكُمۡ تَهۡتَدُونَ ﴾
[البَقَرَة: 53]
﴿وإذ آتينا موسى الكتاب والفرقان لعلكم تهتدون﴾ [البَقَرَة: 53]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Ẹ rántí) nígbà tí A fún (Ànábì) Mūsā ní Tírà àti ọ̀rọ̀-ìpínyà nítorí kí ẹ lè mọ̀nà |