Quran with Yoruba translation - Surah Al-Baqarah ayat 52 - البَقَرَة - Page - Juz 1
﴿ثُمَّ عَفَوۡنَا عَنكُم مِّنۢ بَعۡدِ ذَٰلِكَ لَعَلَّكُمۡ تَشۡكُرُونَ ﴾
[البَقَرَة: 52]
﴿ثم عفونا عنكم من بعد ذلك لعلكم تشكرون﴾ [البَقَرَة: 52]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Lẹ́yìn náà, A mójú kúrò fun yín lẹ́yìn ìyẹn nítorí kí ẹ lè dúpẹ́ (fún Allāhu) |