Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 101 - طه - Page - Juz 16
﴿خَٰلِدِينَ فِيهِۖ وَسَآءَ لَهُمۡ يَوۡمَ ٱلۡقِيَٰمَةِ حِمۡلٗا ﴾
[طه: 101]
﴿خالدين فيه وساء لهم يوم القيامة حملا﴾ [طه: 101]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Olùṣegbére ni wọ́n nínú (ìyà) rẹ̀. (Ẹrù ẹ̀ṣẹ̀) sì burú fún wọn láti rù ní Ọjọ́ Àjíǹde |