Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 100 - طه - Page - Juz 16
﴿مَّنۡ أَعۡرَضَ عَنۡهُ فَإِنَّهُۥ يَحۡمِلُ يَوۡمَ ٱلۡقِيَٰمَةِ وِزۡرًا ﴾
[طه: 100]
﴿من أعرض عنه فإنه يحمل يوم القيامة وزرا﴾ [طه: 100]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹnikẹ́ni tí ó bá gbúnrí kúrò níbẹ̀, dájúdájú ó máa ru ẹrù ẹ̀ṣẹ̀ ní Ọjọ́ Àjíǹde |