Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 118 - طه - Page - Juz 16
﴿إِنَّ لَكَ أَلَّا تَجُوعَ فِيهَا وَلَا تَعۡرَىٰ ﴾
[طه: 118]
﴿إن لك ألا تجوع فيها ولا تعرى﴾ [طه: 118]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú ebi kò níí pa ọ́, o ò sì níí rìn hòhò nínú rẹ̀ |