Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 48 - طه - Page - Juz 16
﴿إِنَّا قَدۡ أُوحِيَ إِلَيۡنَآ أَنَّ ٱلۡعَذَابَ عَلَىٰ مَن كَذَّبَ وَتَوَلَّىٰ ﴾
[طه: 48]
﴿إنا قد أوحي إلينا أن العذاب على من كذب وتولى﴾ [طه: 48]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú Wọ́n ti fi ìmísí ránṣẹ́ sí wa pé dájúdájú ìyà ń bẹ fún ẹni tí ó bá pe òdodo nírọ́, tí ó sì kẹ̀yìn sí i |