Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 57 - طه - Page - Juz 16
﴿قَالَ أَجِئۡتَنَا لِتُخۡرِجَنَا مِنۡ أَرۡضِنَا بِسِحۡرِكَ يَٰمُوسَىٰ ﴾
[طه: 57]
﴿قال أجئتنا لتخرجنا من أرضنا بسحرك ياموسى﴾ [طه: 57]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó wí pé: "Ṣé o wá bá wa nítorí kí o lè mú wa jáde kúrò lórí ilẹ̀ wa pẹ̀lú idán rẹ ni, Mūsā |