Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 56 - طه - Page - Juz 16
﴿وَلَقَدۡ أَرَيۡنَٰهُ ءَايَٰتِنَا كُلَّهَا فَكَذَّبَ وَأَبَىٰ ﴾
[طه: 56]
﴿ولقد أريناه آياتنا كلها فكذب وأبى﴾ [طه: 56]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú A ti fi àwọn àmì Wa hàn án, gbogbo rẹ̀. Àmọ́ ó pè é nírọ́. Ó sì kọ̀ jálẹ̀ |