Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 70 - طه - Page - Juz 16
﴿فَأُلۡقِيَ ٱلسَّحَرَةُ سُجَّدٗا قَالُوٓاْ ءَامَنَّا بِرَبِّ هَٰرُونَ وَمُوسَىٰ ﴾
[طه: 70]
﴿فألقي السحرة سجدا قالوا آمنا برب هارون وموسى﴾ [طه: 70]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, iṣẹ́ ìyanu (Ànábì Mūsā) mú àwọn òpìdán dojú bolẹ̀ ní olùforíkanlẹ̀ (fún Allāhu). Wọ́n wí pé: "A gbàgbọ́ nínú Olúwa Hārūn àti Mūsā |