Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 78 - طه - Page - Juz 16
﴿فَأَتۡبَعَهُمۡ فِرۡعَوۡنُ بِجُنُودِهِۦ فَغَشِيَهُم مِّنَ ٱلۡيَمِّ مَا غَشِيَهُمۡ ﴾
[طه: 78]
﴿فأتبعهم فرعون بجنوده فغشيهم من اليم ما غشيهم﴾ [طه: 78]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Fir‘aon sì tẹ̀lé wọn pẹ̀lú àwọn ọmọ ogun rẹ̀. Ohun tí ó bò wọ́n mọ́lẹ̀ dáru nínú agbami odò sì bò wọ́n mọ́lẹ̀ dáru |