Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 112 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿قَٰلَ رَبِّ ٱحۡكُم بِٱلۡحَقِّۗ وَرَبُّنَا ٱلرَّحۡمَٰنُ ٱلۡمُسۡتَعَانُ عَلَىٰ مَا تَصِفُونَ ﴾
[الأنبيَاء: 112]
﴿قال رب احكم بالحق وربنا الرحمن المستعان على ما تصفون﴾ [الأنبيَاء: 112]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó sọ pé: “Olúwa mi, ṣèdájọ́ pẹ̀lú òdodo. Olúwa wa ni Àjọkẹ́-ayé, Olùrànlọ́wọ́ lórí ohun tí ẹ̀ ń fi ròyìn (Rẹ̀).” |