Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 16 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿وَمَا خَلَقۡنَا ٱلسَّمَآءَ وَٱلۡأَرۡضَ وَمَا بَيۡنَهُمَا لَٰعِبِينَ ﴾
[الأنبيَاء: 16]
﴿وما خلقنا السماء والأرض وما بينهما لاعبين﴾ [الأنبيَاء: 16]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwa kò dá sánmọ̀ àti ilẹ̀ àti ohun tí ń bẹ láààrin àwọn méjèèjì pẹ̀lú eré ṣíṣe |