Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 65 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿ثُمَّ نُكِسُواْ عَلَىٰ رُءُوسِهِمۡ لَقَدۡ عَلِمۡتَ مَا هَٰٓؤُلَآءِ يَنطِقُونَ ﴾
[الأنبيَاء: 65]
﴿ثم نكسوا على رءوسهم لقد علمت ما هؤلاء ينطقون﴾ [الأنبيَاء: 65]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Lẹ́yìn náà, wọ́n sorí kọ́ (wọ́n sì wí pé): “Ìwọ náà kúkú mọ̀ pé àwọn wọ̀nyí kì í sọ̀rọ̀.” |