Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 64 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿فَرَجَعُوٓاْ إِلَىٰٓ أَنفُسِهِمۡ فَقَالُوٓاْ إِنَّكُمۡ أَنتُمُ ٱلظَّٰلِمُونَ ﴾
[الأنبيَاء: 64]
﴿فرجعوا إلى أنفسهم فقالوا إنكم أنتم الظالمون﴾ [الأنبيَاء: 64]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nígbà náà, wọ́n yíjú síra wọn, wọ́n sì wí pé: “Dájúdájú ẹ̀yin ni alábòsí.” |