Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 66 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿قَالَ أَفَتَعۡبُدُونَ مِن دُونِ ٱللَّهِ مَا لَا يَنفَعُكُمۡ شَيۡـٔٗا وَلَا يَضُرُّكُمۡ ﴾
[الأنبيَاء: 66]
﴿قال أفتعبدون من دون الله ما لا ينفعكم شيئا ولا يضركم﴾ [الأنبيَاء: 66]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó sọ pé: "Ṣé ẹ̀yin yóò máa jọ́sìn fún n̄ǹkan tí kò lè ṣe yín ní àǹfààní, tí kò sì lè kó ìnira ba yín lẹ́yìn Allāhu |