Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 71 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿وَنَجَّيۡنَٰهُ وَلُوطًا إِلَى ٱلۡأَرۡضِ ٱلَّتِي بَٰرَكۡنَا فِيهَا لِلۡعَٰلَمِينَ ﴾
[الأنبيَاء: 71]
﴿ونجيناه ولوطا إلى الأرض التي باركنا فيها للعالمين﴾ [الأنبيَاء: 71]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A sì gba òun àti Lūt là sórí ilẹ̀ tí A fi ìbùkún sí fún gbogbo ẹ̀dá |